Ossain
YO

Ossain লিরিক্স

অ্যালবামGira Mundo
বছর2025
ধরনPop
মূল ভাষাYO
ভিউ172
Aaপাঠ সেটিং
টেক্সট সাইজ 18

মূল লিরিক্স

YO
Translation not available yet. Showing the original lyrics.
Ewá já le orí a t'orí Oríre wa t'ori A ki uṣẹ Irúnmọlẹ A nsábá bàbá bárò A nsábá bàbá pèètú òo Ojú oró alá furu ìkán Oríre wa t'ori bàbá pèètú Oríre wa t'ori (Ewá já le orí a t'orí) (Oríre wa t'ori) (A ki uṣẹ Irúnmọlẹ) (A nsábá bàbá bárò) (A nsábá bàbá pèètú òo) (Ojú oró alá furu ìkán) (Oríre wa t'ori bàbá pèètú) (Oríre wa t'ori) Ewá já le orí a t'orí Oríre wa t'ori A ki uṣẹ Irúnmọlẹ A nsábá bàbá bárò A nsábá bàbá pèètú òo Ojú oró alá furu ìkán Oríre wa t'ori bàbá pèètú Oríre wa t'ori Oríre wa t'ori bàbá pèètú Oríre wa t'ori Farabalẹ̀ ki o súnmọ Farabalẹ̀ ki o súnmọ Kun-kun Olorí ewé Farabalẹ̀ ki o súnmọ (Farabalẹ̀ ki o súnmọ) (Farabalẹ̀ ki o súnmọ) (Kun-kun Olorí ewé) (Farabalẹ̀ ki o súnmọ) Farabalẹ̀ ki o súnmọ Farabalẹ̀ ki o súnmọ Kun-kun Olorí ewé Farabalẹ̀ ki o súnmọ (Farabalẹ̀ ki o súnmọ) (Farabalẹ̀ ki o súnmọ) (Kun-kun Olorí ewé) (Farabalẹ̀ ki o súnmọ) Ewé ni ọ̀ rọ Ọ̀ rọ̀ ki a má ni òo! Ewé ni ọ̀ rọ Ọ̀ rọ̀ ki a má ni òo! Ewé ni ọ̀ rọ Ọ̀ rọ̀ ki a má ni òo! (Ewé ni ọ̀ rọ) Ọ̀ rọ̀ ki a má ni òo! (Ewé ni ọ̀ rọ) Ọ̀ rọ̀ ki a má ni òo! (Ewé ni ọ̀ rọ) Ọ̀ rọ̀ ki a má ni òo! (Ewé ni ọ̀ rọ) Ọ̀ rọ̀ ki a má ni òo! (Ewé ni ọ̀ rọ) Oríre wa t'ori bàbá pèètú Oríre wa t'ori (bàbá pèètú) Oríre wa t'ori

Majur এর আরও গান

Majur →

সম্পর্কিত লিরিক্স