A Le Tente
YO

Testo di A Le Tente

GenereAfrobeats
Lingua originaleYO
Visualizzazioni6
AaLettura
Dimensione 18

Testo originale

YO
Traduzione non ancora disponibile. Mostriamo il testo originale.
T'a l'ó wà ní'bẹ? T'a l'ó wà, t'á ó pè ní'ṣẹ'? Àwọn ọrẹ wa wọn wà ní'bẹ', wọn pọ t'a pè ní'ṣẹ o Wọn mí w'ọ'nà f'ẹ'ni ńṣì'nà Wọn mí là'nà f'ẹ'ni nrìn bọ' Wọn mí gb'èrò wípé k'ó lè da Wọn mí ṣ'ìpẹ' f'ẹ'ni nṣ'ọ'fọ' Wọn mí pèsè f'aláìrí Wọn mí ṣè'tò wípé, wípé k'ó lè da Ẹgbẹ aláyọ', ẹgbẹ'oníre ńpè yín sẹ Àwọn ọrẹ wa wọn wà ní'bẹ', wọn pọ' t'a pè ní'ṣẹ o Wọn mí gbè'jà f'ẹ'ni ńjà'jà rere Wọn mí p'ẹ'tù sí'nú fùfù Wọn mí gb'èrò wípé k'ó lè da o Wọn mí wò'kè f'ẹ'ni ńwo'lẹ Wọn mí wo'lẹ' f'ẹ'ni ńwòké Wọn mí ṣè'tò wípé, wípé k'ó lè da Gbogbo ẹdá mà la pè, gbogbo yín mà la pè ní'ṣẹ' Àwọn ọrẹ wa wọn wà ní'bẹ', wọn pọ t'a pè ní'ṣẹ o Wọn mí w'ọ'nà f'ẹ'ni ńṣì'nà Wọn mí là'nà f'ẹ'ni ńrìn bọ Wọn mí gb'èrò wípé k'ó lè da o Wọn mí ṣ'ìpẹ' f'ẹ'ni ńṣ'ọfọ Wọn mí pèsè f'aláìrí Wọn mí ṣè'tò wípé, wípé k'ó lè da o Wọn mí gbè'jà f'ẹ'ni ńjà'jà rere Wọn mí p'ẹ'tù sí'nú fùfù Wọn mí gb'èrò wípé k'ó lè da o Wọn mí wò'kè f'ẹ'ni ńwo'lẹ Wọn mí wo'lẹ' f'ẹ'ni ńwò'kè Wọn mí ṣè'tò wípé, wípé k'ó lè da À fò, à lé ténté, à fò àwa d'ọ'rẹ' ìdùnnú (À fò, à lé ténté, à fò) àwa jogún ìdẹ'ra (À fò, à lé ténté, à fò) àwa bo'rí àìmọkan (À fò, à lé ténté, à fò) àwa bo'rí ìkórira (À fò, à lé ténté, à fò) àwa bo'rí ìwà ibi (À fò, à lé ténté, à fò) àwa d'ọrẹ ìdùnnú (À fò, à lé ténté, à fò) àwa jogún ìdẹ'ra

Altro di Beautiful Nubia And The Roots Renaissance Band

Beautiful Nubia And The Roots Renaissance Band →

Testi correlati