For Arike
YO

For Arike کے بول

صنفAfrobeats
اصل زبانYO
مناظر176
Aaپڑھنے کی ترتیبات
متن کا سائز 18

اصل بول

YO
ترجمہ ابھی دستیاب نہیں۔ اصل بول دکھائے جا رہے ہیں۔
Olólùfẹ' àwa, ọmọ Àríkẹ Ṣebí'wọ lo l'òní o, a dùn wò Gbogbo ayé mà mí s'àfẹ'rí rẹ Jíjó rẹ fún wa ká yọ' mọọ l'óde Rọra, máa gb'ẹsẹ ní kànkan Rọra máa gb'ẹsẹ ní kànkan Oníwàtútù yí, ọmọ ìwúrí Ṣèbí'wọ lo pè wá jọ, a mà dé o Ojú rẹ dùn wò, ó ń dá ni l'ọ'rùn Sùgbọn, iwà rẹ lo fi tàn bí òṣùpá Ilé rẹ wùn wá o, ká jọ dé'bẹ Ilé rẹ wùn wá o, ká jọ dé'bẹ' Ṣa ma ṣe tìrẹ o, ọmọ àrídunnú Má wo t'àwọn ẹlẹ'gàn agbẹ'yìnṣebi Òjòwú ayé ọ'tá ìlọsíwájú N'ọwọ' rẹ s'ókè k'o dì mọ're òní Olólùfẹ' àwa, Àríkẹ' gẹgẹ Olólùfẹ' àwa, Àríkẹ' gẹgẹ Omọ'gbẹ'kọ, arẹwà, adáraníjó Bó bá s'ọgbọn, o ní yẹn, oò rẹ'wẹ'sì Iṣẹ' ọwọ' rẹ mà gbé ọ lékè Inú àwa mà ń dùn láti mọ' ọ Ìjòkó ẹyẹ rẹ wà l'óde máa bọ Ìjòkó ẹ'yẹ rẹ wà l'óde- Gbé'ra n'ílẹ', òní l'ọjọ' iyì rẹ À dé, à bá ẹ yọ Olólùfẹ àwa, ọmọ Àríkẹ Ṣebí'wọ lo l'òní o, a dùn wò Gbogbo ayé mà mí s'àfẹ'rí rẹ Jíjó rẹ fún wa ká yọ' mọ' ọ l'óde Rọra máa gb'ẹ'sẹ' ní kànkan Rọra máa gb'ẹ'sẹ' ní kànkan Omọ'gbẹ'kọ', arẹwà, adáraníjó Bó bá s'ọgbọn, o ní yẹn, oò rẹ'wẹ'sì Iṣẹ' ọwọ' rẹ mà gbé ọ lékè Inú àwa mà ń dùn láti mọ' ọ Ìjòkó ẹ'yẹ rẹ wà l'óde, máa bọ' Ìjòkó ẹ'yẹ rẹ wà l'óde, máa bọ Ìjòkó ẹ'yẹ rẹ wà l'óde, máa bọ Ìjòkó ẹ'yẹ rẹ wà l'óde- Gbé'ra n'ílẹ', òní l'ọjọ' iyì rẹ À dé, a bá ẹ yọ' À dé, a bá ẹ yọ' (a dé, a bá ẹ yọ') Ẹgbẹ Aládùn Onílé, a ba ẹ yọ (a dé, a bá ẹ yọ') a dé, a bá ẹ yọ À dé, a bá ẹ yọ' (a dé, a bá ẹ yọ') Ẹgbẹ Aládùn Onílé, a ba ẹ yọ (a dé, a bá ẹ yọ') a dé, a bá ẹ yọ À dé, a bá ẹ yọ' (a dé, a bá ẹ yọ') Ẹgbẹ Aládùn Onílé, a ba ẹ yọ (a dé, a bá ẹ yọ') a dé, a bá ẹ yọ' À dé, a bá ẹ yọ' (a dé, a bá ẹ yọ') Ẹgbẹ Aládùn Onílé, a ba ẹ yọ (a dé, a bá ẹ yọ') a dé, a bá ẹ yọ' À dé, a bá ẹ yọ' (a dé, a bá ẹ yọ')

Beautiful Nubia And The Roots Renaissance Band کے مزید گیت

Beautiful Nubia And The Roots Renaissance Band →

متعلقہ بول