Showa
English

Showa کے بول

صنفPop
اصل زبانEnglish
مناظر59
Aaپڑھنے کی ترتیبات
متن کا سائز 18

اصل بول

EN
ترجمہ ابھی دستیاب نہیں۔ اصل بول دکھائے جا رہے ہیں۔
(Zed) Ahn-ahn Alákọri, alakọkọ, ṣ'ómá fẹ mí? Ṣ'ómá là tán? Tí ń bà gbé wá (whoo), ṣ'ómá ká kọ? Ṣé mo máa ní problem pẹlú boys? Ta bà já, ká padà, má sá lọ Canada If I travel today, kí ń má bà ẹ l'ababa (l'ababa) Army man na my army man Army man na my brother man Ó lè ní problem Ahh, baby, ṣ'ówa pá oh? (Ṣ'ówá pá?) Ṣó need mi kì ń call in? (Àwọn eléyìí) Mo láyé lo máa jẹ kù o Ìrù eléyìí ó mà ní problem (kan) Melanin poppin', baby, nìṣó ní tá Baby, sunshine give you filter Onidiri ńbẹ, oh-yeah, oh-wururu rarurábà (Ṣ'owá?) Ṣ'òní capital business? (Ṣ'owá?) Ṣ'òní character deaconess? (Ṣ'owá?) Can you wake up around 4: 30 (ṣ'owá?) To make breakfast for me? (Ṣ'owá?) Tó bà dálẹ, ṣ'olè gimme-gimme? (Ṣ'owá?) Gimme-gimme, kò má gbọn mí jìgì (ṣ'owá?) Gimme-gimme, k'oma gbọn mi jigi (ṣ'owá?) Oh-ooh-oh Long time ago, I say no kele fit make me conform, ooh-yah Ò ká mí mọ corner (ṣ'ó) Now, I won do am, now, I won run am (oya, uh) Very gentle girl (whoo) I'll pick you up, turn you biggie girl (biggie girl) Mama say: I don fall in love And my papa say: Ọmọ, jẹun lọ Ahh, baby, ṣ'ówa pá oh? (Ṣ'ówá pá?) Ṣó need mi kì ń call in? (Àwọn eléyìí) Mo láyé lo máa jẹ kù o Ìrù eléyìí ó mà ní problem (kan) Melanin popping, baby, nìṣó ní tá Baby, sunshine give you filter Onidiri ńbẹ, oh-yeah, oh-wururu, rarurábà (Ṣ'owá?) Ṣ'òní capital business? (Ṣ'owá?) Ṣ'òní character deaconess? (Ṣ'owá?) Can you wake up around 4: 30 (ṣ'owá?) To make breakfast for me? (Ṣ'owá?) Tó bà dálẹ, ṣ'olè gimme-gimme? (Ṣ'owá?) Gimme-gimme, kò má gbọn mí jìgì (ṣ'owá?) Gimme-gimme, k'oma gbọn mi jigi (ṣ'owá?) Oh-ooh-oh (Ṣ'owá?) (Ṣ'owá?) (Ṣ'owá?) (Ṣ'owá?) Oh-ooh-oh (Ṣ'owá?) (Ṣ'owá?) (Ṣ'owá?) (Ṣ'owá?) Oh-ooh-oh

Kizz Daniel کے مزید گیت

Kizz Daniel →

متعلقہ بول