Aimokan
YO

Aimokan के बोल

शैलीAfrobeats
मूल भाषाYO
व्यूज़14
Aaपढ़ने की सेटिंग
टेक्स्ट आकार 18

मूल बोल

YO
Translation not available yet. Showing the original lyrics.
Ṣ'ówó ló wùn ọ', t'ó ń wá, t'ó ń sá'ré kìràkìtà? Àbí 'lé lo fẹ' kọ', tó gùn ọ' l'ọ'kàn, t'ó nbẹ' jàùjàù o? Kò sí're t'á ńfẹ tí ẹ'dá kò ní rí, b'ásìkò bá tó o K'á ṣáà ma wù'wà 're, l'ó tọ' o K'a ṣáà ma wù'wà gidi, ọrẹ'mi, l'áyé Mo rí ọ t'o gb'ẹ'rù l'órí l'ọ'sán tí òòrùn tàn yanyan Mo tún rí ọ l'ọ'gànjọ' t'o gbé'un s'éjìká nmí hílàhílo o Bó ti wù k'ó ti rí, ire ẹ'dá kò ní kọjá rẹ', b'ópẹ', b'óyá o K'á ṣáà ní sùúrù l'ó tọ' o K'á ṣáà n'ítẹ'lọ'rùn, ọrẹ mi, l'áyé Ilara ò l'érè (ilara ò l'érè o), ẹ gbọ' mi, ó ńsọ ni d'èrò ẹ'yìn ni Òòrùn ò ní ràn títí, títí (ràn títí o) k'ó gba 'ṣẹ' òṣùpá ṣe l'ókè Ojú ọ'run t'ẹ'yẹ fò lẹ'gbẹgbẹ'rún l'áì f'ara kan'ra o K'á ṣáà l'áforítì l'ó tọ' o K'á ṣáà n'íwà tútù, ọ'rẹ' mi, l'áyé Ṣ'ọgbọn l'ó wùn ọ', t'ó nwá (ọgbọn l'ó wùn ọ'), t'ó nbẹ' gìjàgìjà kiri? Àbí'yì l'ò nfẹ', kí gbogbo ayé máa wá rìrì fún ẹ o? Ire ò ní kọjá on'íre, ojú mà níí pẹ' sí o K'á ṣáà ma wù'wà 're, l'ó to o K'á ṣáà ma wù'wà gidi, ọrẹ mi, l'áyé Àìmọ'kan l'ó ń dàmú ẹ'dá o L'ó ń dàmú ènìyàn, t'ó nṣè'páyà fún ọla Ìgbà àwa yió l'ádùn gan, yió láyọ púpọ' K'á ṣáà ma wù'wà 're, l'ó tọ' o K'á ṣáà ma wù'wà gidi, ọrẹ mi, l'áyé L'ó ndàmú ènìyàn, t'ó ń ṣè'páyà fún ọ'la (Ìgbà àwa yió l'ádùn gan) yió láyọ púpọ' K'á sáà ma wù'wà 're, l'ó tọ' o (K'á sáà ma wù'wà gidi) ọrẹ mi, l'áyé L'ó ń dàmú ènìyàn, t'ó ńṣè'páyà fún ọ'la (Ìgbà àwa yió l'ádùn gan) yió láyọ púpọ' K'á ṣáà ma wù'wà 're, l'ó tọ o (K'á ṣáà ma wù'wà gidi) ọrẹ mi, l'áyé L'ó ń dàmú ènìyàn, t'ó ńṣè'páyà fún ọ'la (Ìgbà àwa yió l'ádùn gan) yió láyọ' púpọ' K'á ṣáà ma wù'wà 're, l'ó tọ o (K'á ṣáà ma wù'wà gidi) ọ'rẹ' mi, l'áyé K'á ṣáà ma wù'wà 're, l'ó tọ o (k'á ṣáà ma wù'wà gidi) K'á ṣáà ma wù'wà 're, l'ó tọ' o (k'á ṣáà ma wù'wà gidi) K'á ṣáà ma wù'wà 're, l'ó tọ o

Beautiful Nubia And The Roots Renaissance Band के और गीत

Beautiful Nubia And The Roots Renaissance Band →

संबंधित गीत