Olú Ọdẹ
YO

Olú Ọdẹ के बोल

शैलीAfrobeats
मूल भाषाYO
व्यूज़11
Aaपढ़ने की सेटिंग
टेक्स्ट आकार 18

मूल बोल

YO
Translation not available yet. Showing the original lyrics.
Olu Ọdẹ nde o (ye, nde o) Olu Ọdẹ nde o (ye, nde o) Olu Ọdẹ nde o (ye, nde o) Eemọ wọ'lu o, o ko'ni l'oun lọ Ijamba ma de o, o n bu rara Arinka wọ'lu o, o mi pe o ni'ja Olu Ọdẹ nde o (ye, nde o) Olu Ọdẹ nde o (ye, nde o) Olu Ọdẹ nde o (ye, nde o) Eemọ wọ'lu o, o ko'ni l'oun lọ Ijamba ma de o, o n bu rara Arinka wọ'lu o, o mi pe o ni'ja Oluwa mi, ogirigbamugbamugidigba o ṣe'la Baba mi, igi agunla ṣedi bẹbẹrẹ s'ọpọn aye Baba mi, ìmọ́lẹ̀-taanran-bori-ookun-biri Asape-asala, o-s'opo-d'ọlá, sọ'wọfa d'oyin Okitiribiti, ko ṣe mì, ko ṣe yi, a-gbe-ni-gun-la Ina fuuru jo lor'omi, ko-ṣe-dimu, ko-ṣe-fiilẹ Baba mi, opo-a-lọ-mọ-ye, a-fo-mọ-la Awo're ti n gb'ọmọ l'ọjọ ewu Oluwa mi, nde! Olu Ọdẹ o ma w'ọmọ rẹ o (ko ma w'ọmọ rẹ) Olu Ọdẹ o ma w'aya rẹ o (ko ma w'aya rẹ) Olu Ọdẹ o ma w'ẹni rẹ o (ko ma w'ẹni rẹ) Eemọ wọ'lu o, o ko'ni l'oun lọ Ijamba ma de o, o n bu rara Arinka wọ'lu o, o mi pe o ni'ja Olu Ọdẹ nde o (ye, nde o) Olu Ọdẹ nde o (ye, nde o) Olu Ọdẹ o ma w'ọmọ rẹ o (ko ma w'ọmọ rẹ) Olu Ọdẹ nde o (ye, nde o) Olu Ọdẹ nde o (ye, nde o) Olu Ọdẹ o ma w'aya rẹ o (ko ma w'aya rẹ) Olu Ọdẹ nde o (ye, nde o) Olu Ọdẹ nde o (ye, nde o) Olu Ọdẹ o ma w'ẹni rẹ o (ko ma w'ẹni rẹ) Olu Ọdẹ nde o (ye, nde o) Olu Ọdẹ nde o (ye, nde o) Olu Ọdẹ o ma w'ọmọ rẹ o (ko ma w'ọmọ rẹ) Ye-

Beautiful Nubia And The Roots Renaissance Band के और गीत

Beautiful Nubia And The Roots Renaissance Band →

संबंधित गीत