Eefo Egbe
YO

Eefo Egbe के बोल

शैलीAfrobeats
मूल भाषाYO
व्यूज़20
Aaपढ़ने की सेटिंग
टेक्स्ट आकार 18

मूल बोल

YO
Translation not available yet. Showing the original lyrics.
Ẹgbẹ aládùn lo mí pé wá, wa ka lọ o (Kà má'yọ wálé) jẹ ká lọ o (ma fòyà) Ẹgbẹ onire lo mí pe wá o, wá ká lọ o (Kà má dùn wálé) 'ni ko jẹ ká lọ o (má bẹ̀rù) Ìgbìmọ̀ Ẹgbẹ', a mu're wọ'lú Ìgbìmọ̀ Ẹgbẹ', onínúre o Ìgbìmọ̀ Ẹgbẹ', atunluto Abaniṣe, k'ọlá ko lé dùn Ìgbìmọ̀ Ẹgbẹ', a mu're wọ'lú Ìgbìmọ̀ Ẹgbẹ', onínúre o Ìgbìmọ̀ Ẹgbẹ', atunluto Abaniṣé, k'ọlá kò lé to Ẹgbẹ aládùn lo mí pé wá o, wa ka lọ o (Kà má'yọ wálé) jẹ ká lọ o (ma fòyà) Ẹgbẹ onire lo mí pe wá o, wá ká lọ o (Kà má dùn wálé) 'ni kò jẹ ká lọ o (má bẹ̀rù) Ke sọmọdé pel'àgbààgbà o Ọkùnrin ìlù, oninure o Ke s'àwọn ọdọ, ìrètí ọ'la Àwọn ọmọ ọ'la, ọmọ ọgbọn Ke sọmọdé pel'àgbààgbà o Obìnrin ìlú, oninure o Ke s'àwọn ọdọ, ìrètí ọlá Àwọn ọmọ iyì, ọmọ ọgbọn Ẹgbẹ aládùn lo mí pé wá o, wa ka lọ o (Kà má'yọ wálé) jẹ ká lọ o (ma fòyà) Ẹgbẹ onire lo mí pe wá, wá ká lọ o (Kà má dùn wálé) ani ko jẹ ká lọ o (má bẹ̀rù) Ìgbìmọ̀ Ẹgbẹ', a mu're wọ'lú Ìgbìmọ̀ Ẹgbẹ', onínúre o Ìgbìmọ̀ Ẹgbẹ', atunluto Abaniṣe, k'ọlá ko lé dùn Ìgbìmọ̀ Ẹgbẹ', a mu're wọ'lú Ìgbìmọ̀ Ẹgbẹ', onínúre o Ìgbìmọ̀ Ẹgbẹ', atunluto Abaniṣé, k'ọlá kò lé to Ke sọmọdé pel'àgbààgbà o Ọkùnrin ìlù, oninure o Ke s'àwọn ọdọ, ìrètí ọ'la Àwọn ọmọ ọ'la, ọmọ ọgbọn Ke sọmọdé pel'àgbààgbà o Obìnrin ìlú, oninure o Ke s'àwọn ọdọ, ìrètí ọlá Àwọn ọmọ iyì, ọmọ ọgbọn Ẹgbẹ aládùn lo mí pé wá o, wa ka lọ o (Kà má'yọ wálé) 'ni ko jẹ ká lọ o (ma fòyà) Ẹgbẹ onire lo mí pe wá, wá ká lọ o (Kà má dùn wálé) ọrẹ mí, jẹ ká lọ o (má bẹ̀rù) Wa ka lọ Jẹ ká lọ o Ey-ey, oh-e, ey-ey (kà má'yọ wálé, ma fòyà) Wa ka lọ Ey-ey, oh-e, ey-ey (kà má dùn wálé, má bẹ̀rù) Wà ká lọ Ey-ey, oh-e, ey-ey (kà má'yọ wálé, ma fòyà) Wà ká lọ

Beautiful Nubia And The Roots Renaissance Band के और गीत

Beautiful Nubia And The Roots Renaissance Band →

संबंधित गीत