EniObanke Gangan
YO

EniObanke Gangan के बोल

शैलीAfrobeats
मूल भाषाYO
व्यूज़5
Aaपढ़ने की सेटिंग
टेक्स्ट आकार 18

मूल बोल

YO
Translation not available yet. Showing the original lyrics.
Eléré ọba dé, ẹ p'ọ'dọ', ẹ p'àgbà pé'ré yá o Onílù ayọ' ré, ẹ pa'gbo àríyá, ijó yá o Eléré ọba dé, ẹ p'ọ'dọ', ẹ p'àgbà pé'ré yá o Onílù ayọ' ré, ẹ pa'gbo àríyá, ijó yá o Anikú ò ní p'ọmọ rẹ, àrùn ò ní ṣe yín o Ọjọ' òní l'ayọ' rẹ, bẹ'rẹ', tú'jú ká ọ'rẹ' o Ani o bẹ'rẹ', máa jó bẹ'rẹ' máa jó o Dìde máa jó, o ba de nàró maa jó o Onítèmi àtàtà, ẸniỌbánkẹ' gangan F'ẹ'sọ' máa jó, o jàre, f'àyà m'aa jó o Rè'dí o m'aa jó, oba de ra'sẹ' m'aa jó o Onítèmi àtàtà, ẸniỌbánkẹ' gangan Adá'jọ', ọjọ' pé, ara rẹ ò gbà'bọ'dè, tú'ra ká o Onílù ayọ' ré, ẹ pa'gbo àríyá, ijó yá o Adá'jọ', ọjọ' pé, ara rẹ ò gb'odi, tú' ra ká o Onílù ayọ' ré, ẹ pa'gbo àríyá, ijó yá o Ani'kú ò ní p'ọkọ rẹ, àrùn ò ní ṣe yín o Ọjọ' òní l'ayọ' rẹ, bẹ'rẹ', tú'jú ká ọ'rẹ' o Ani o bẹ'rẹ' máa jó bẹ'rẹ' máa jó o Dìde máa jó, o ba de nàró maa jó o Onítèmi àtàtà, ẸniỌbánkẹ' gangan F'ẹ'sọ' máa jó o jàre, f'àyà m'aa jó o Rè'dí o maa jó, ani o ra'sẹ' maa jó o Onítèmi àtàtà, ẸniỌbánkẹ' gangan Ani'kú ò ní p'aya rẹ o, àrùn ò ní ṣe yín o Ọjọ' òní l'ayọ' rẹ, bẹrẹ', tú'jú ka, òré o Ani o bẹ'rẹ' máa jó bẹ'rẹ' máa jó o Dìde o máa jó, a ni o nàró maa jó o Onítèmi àtàtà, ẸniỌbánkẹ' gangan F'ẹ'sọ' máa jó o jàre, f'àyà m'aa jó o Rè'dí o m'aa jó, mo ní o ra'sẹ' maa jó o Onítèmi àtàtà, ẸniỌbánkẹ' gangan

Beautiful Nubia And The Roots Renaissance Band के और गीत

Beautiful Nubia And The Roots Renaissance Band →

संबंधित गीत