Ese Odo
YO

Ese Odo के बोल

शैलीAfrobeats
मूल भाषाYO
व्यूज़5
Aaपढ़ने की सेटिंग
टेक्स्ट आकार 18

मूल बोल

YO
Translation not available yet. Showing the original lyrics.
Òun méjì l'o mọ, ò mọ t'ẹní t'o mọ méjìlá Òun mẹ'rin l'o mọ o, ò mọ t'ẹní to mọ mẹ́rìnlá O wá ń ké, Wo-wo-wo, o mí ké, Wiriwiri (warawara) O ń ro, Pin-pin-pin, o mí dùn, Huruhara (harahuru) O wá ń ké, Wo-wo-wo, o mí ké, Wiriwiri (warawara) O ńro, Pin-pin-pin, o mí dùn, Huruhara Kí lo ń bẹ l'oko o, t'akíkanjú o rí rí? Kí ní ńbọ' l'aginjù t'ọdẹ àgbà oi rìn kàn? Àní, ko bà ké, Wo-wo (ọdẹ a dákẹ́ pin-pin) Bò bá bú ra-ra (àgbà a múra ìjà silẹ) Bò bá yi'ra padà (ọdẹ a t'àgbàrá ṣé) Ah, bò bá wá d'omi, ìpàdé d'ẹsẹ O d'ẹsẹ odò (odò) Ìpàdé d'ẹsẹ odò, oh-oh (odò) O d'ẹsẹ odò (odò) Ìpàdé d'ẹsẹ odò, oh-oh (odò) Òun méjì l'o mọ, ò mọ t'ẹní t'o mọ méjìlá Òun mẹ'rin l'o mọ o, ò mọ t'ẹní to mọ mẹ́rìnlá O wá ń ké, Wo-wo-wo, o mí ké, Wiriwiri (warawara) O ń ro, Pin-pin-pin, o mí dùn, Huruhara (harahuru) O wá ń ké, Wo-wo-wo, o mí ké, Wiriwiri (warawara) O ńro, Pin-pin-pin, o mí dùn, Huruhara Kí lo ń bẹ l'oko o, t'akíkanjú o rí rí? Kí ní ńbọ' l'aginjù t'ọdẹ àgbà oi rìn kàn? Àní, ko bà ké, Wo-wo (ọdẹ a dákẹ́ pin-pin) Bò bá bú ra-ra (àgbà a múra ìjà silẹ) Bò bá yi'ra padà (ọdẹ a t'àgbàrá ṣé) Ah, bò bá wá d'omi o, ìpàdé d'ẹsẹ O d'ẹsẹ odò (odò) Ìpàdé d'ẹsẹ odò, oh-oh (odò) Ah, o d'ẹsẹ odò (odò) Ìpàdé d'ẹsẹ odò, oh-oh (odò)

Beautiful Nubia And The Roots Renaissance Band के और गीत

Beautiful Nubia And The Roots Renaissance Band →

संबंधित गीत