Omoniyun
YO

Omoniyun के बोल

शैलीAfrobeats
मूल भाषाYO
व्यूज़4
Aaपढ़ने की सेटिंग
टेक्स्ट आकार 18

मूल बोल

YO
Translation not available yet. Showing the original lyrics.
Ọwọ mí òsì, ọwọ mí òtún Ọwọ mí méjèèjì máa fí gb'ọmọ jó o Ọwọ mí òsì, ọwọ mí òtún Ọwọ mí méjèèjì máa fí gb'ọmọ jó o Ọwọ mí òsì, ọwọ mí òtún Ọwọ mí méjèèjì máa fí gb'ọmọ jó o Ọwọ mí òsì, ọwọ mí òtún Ọwọ mí méjèèjì máa fí gb'ọmọ jó o Ọmọ ní pe ní l'ọjà ayé Ọmọniyun, ọmọnídè, ọmọ ní wúrà Ọmọ l'àwòrán eré o Ọmọ ní pe ní l'ọjà ayé Ọmọniyun, ọmọnídè, ọmọ ní wúrà Ọmọ l'àwòrán eré o Ọwọ mí òsì, ọwọ mí òtún Ọwọ mí méjèèjì máa fí gb'ọmọ jó o Mà yọ ṣẹ'ṣẹ' (Bí à fún mí tọ) inú mí à dùn geere Ọmọniyun, ọmọnídè, ọmọ ní wúrà o Ah, ṣébí kà tí r'ọmọ kẹ ní Ma yo si B'o ṣé l'obìnrin, ayọ rẹpẹtẹ Ọmọniyun, ọmọnídè, ọmọ ní wúrà o Ṣébí kà tí rí kàn kẹ ní Ọwọ mí òsì, ọwọ mí òtún Ọwọ mí méjèèjì máa fí gb'ọmọ jó o Ọmọ ní pe ní l'ọjà ayé Ọmọniyun, ọmọnídè, ọmọ ní wúrà o Ah, ọmọ l'àwòrán eré o (Ọmọ níí wolé dé ni) ọmọ ní pe ní l'ọjà ayé Ọmọniyun, ọmọnídè, ọmọ ní wúrà o Ọmọ l'àwòrán eré o Ọwọ mí òsì, ọwọ mí òtún Ọwọ mí méjèèjì máa fí gb'ọmọ jó o Ọwọ mí òsì, ọwọ mí òtún Ọwọ mí méjèèjì máa fí gb'ọmọ jó o Ọwọ mí òsì, ọwọ mí òtún Ọwọ mí méjèèjì máa fí gb'ọmọ jó o Ọwọ mí òsì, ọwọ mí òtún Ọwọ mí méjèèjì máa fí gb'ọmọ jó o

Beautiful Nubia And The Roots Renaissance Band के और गीत

Beautiful Nubia And The Roots Renaissance Band →

संबंधित गीत